Àìsáyà 21:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí aṣálẹ̀ tó tẹ́jú: Inú igbó, nínú aṣálẹ̀ tó tẹ́jú lẹ máa sùn mọ́jú,Ẹ̀yin ará Dédánì+ tó ń rìnrìn àjò. 14 Ẹ gbé omi wá pàdé ẹni tí òùngbẹ ń gbẹ,Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé ilẹ̀ Témà,+Kí ẹ sì gbé oúnjẹ wá fún ẹni tó ń sá lọ.
13 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí aṣálẹ̀ tó tẹ́jú: Inú igbó, nínú aṣálẹ̀ tó tẹ́jú lẹ máa sùn mọ́jú,Ẹ̀yin ará Dédánì+ tó ń rìnrìn àjò. 14 Ẹ gbé omi wá pàdé ẹni tí òùngbẹ ń gbẹ,Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé ilẹ̀ Témà,+Kí ẹ sì gbé oúnjẹ wá fún ẹni tó ń sá lọ.