Ìdárò 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn ajáko* pàápàá máa ń fún ọmọ wọn lọ́mú,Àmọ́ ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi ti ya ìkà,+ bí àwọn ògòǹgò aginjù.+
3 Àwọn ajáko* pàápàá máa ń fún ọmọ wọn lọ́mú,Àmọ́ ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi ti ya ìkà,+ bí àwọn ògòǹgò aginjù.+