- 
	                        
            
            Jeremáyà 8:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        6 Mo fiyè sí wọn, mo sì ń fetí sílẹ̀, àmọ́ bí wọ́n ṣe sọ̀rọ̀ kò dáa. Kò sí ẹnì kankan tó ronú pìwà dà ìwà burúkú rẹ̀ tàbí kó sọ pé, ‘Kí ni mo ṣe yìí?’+ Kálukú wọn ń pa dà lọ ṣe ohun tí ọ̀pọ̀ èèyàn ń ṣe, bí ẹṣin tó ń já lọ sójú ogun. 
 
-