-
Jóòbù 1:14, 15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 ìránṣẹ́ kan wá bá Jóòbù, ó sì sọ pé: “Àwọn màlúù ń túlẹ̀, àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ sì ń jẹko lẹ́gbẹ̀ẹ́ wọn, 15 ni àwọn Sábéà bá gbógun dé, wọ́n kó wọn, wọ́n sì fi idà pa àwọn ìránṣẹ́. Èmi nìkan ló yè bọ́, tí mo sì wá sọ fún ọ.”
-