-
Jeremáyà 49:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Bí o ṣe ń kó jìnnìjìnnì bá àwọn èèyàn
Àti ìgbéraga* ọkàn rẹ ti tàn ọ́ jẹ,
Ìwọ tó ń gbé ihò inú àpáta,
Tí ò ń gbé ní òkè tó ga jù lọ.
Bí o bá tiẹ̀ kọ́ ìtẹ́ rẹ sí ibi gíga bí ẹyẹ idì,
Màá rẹ̀ ọ́ wálẹ̀ láti ibẹ̀,” ni Jèhófà wí.
-
-
Ọbadáyà 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Bí o bá tiẹ̀ kọ́lé sí ibi gíga* bí ẹyẹ idì,
Tàbí tí o kọ́ ìtẹ́ rẹ sáàárín àwọn ìràwọ̀,
Màá rẹ̀ ọ́ wálẹ̀ láti ibẹ̀,” ni Jèhófà wí.
-