- 
	                        
            
            Jóòbù 9:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        26 Wọ́n ń yára bí ọkọ̀ ojú omi tí wọ́n fi esùsú* ṣe, Bí ẹyẹ idì tó já ṣòòrò wálẹ̀ láti gbé ohun tó fẹ́ pa. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 49:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Ní ọjọ́ yẹn, ọkàn àwọn jagunjagun Édómù Máa dà bí ọkàn obìnrin tó ń rọbí.” 
 
-