-
Jóòbù 38:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Jọ̀ọ́, gbára dì, kí o ṣe bí ọkùnrin;
Màá bi ọ́ ní ìbéèrè, kí o sì dá mi lóhùn.
-
-
Jóòbù 42:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 O sọ pé, ‘Jọ̀ọ́ fetí sílẹ̀, màá sì sọ̀rọ̀.
Màá bi ọ́ ní ìbéèrè, kí o sì dá mi lóhùn.’+
-