-
Jóòbù 37:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Lẹ́yìn náà ni ìró tó ń bú ramúramù;
Ó ń fi ohùn tó ga lọ́lá sán ààrá,+
Kì í sì í dá a dúró tí wọ́n bá gbọ́ ohùn rẹ̀.
-
4 Lẹ́yìn náà ni ìró tó ń bú ramúramù;
Ó ń fi ohùn tó ga lọ́lá sán ààrá,+
Kì í sì í dá a dúró tí wọ́n bá gbọ́ ohùn rẹ̀.