Jóṣúà 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Gbàrà tí àwọn tó gbé Àpótí náà dé Jọ́dánì, tí àwọn àlùfáà tó gbé Àpótí náà sì ki ẹsẹ̀ wọn bọ etí omi náà (ó ṣẹlẹ̀ pé odò Jọ́dánì máa ń kún bo bèbè rẹ̀+ ní gbogbo ọjọ́ ìkórè),
15 Gbàrà tí àwọn tó gbé Àpótí náà dé Jọ́dánì, tí àwọn àlùfáà tó gbé Àpótí náà sì ki ẹsẹ̀ wọn bọ etí omi náà (ó ṣẹlẹ̀ pé odò Jọ́dánì máa ń kún bo bèbè rẹ̀+ ní gbogbo ọjọ́ ìkórè),