Sáàmù 40:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wo bí àwọn ohun tí o ṣe ti pọ̀ tó,Jèhófà Ọlọ́run mi,Àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ àti èrò rẹ sí wa.+ Kò sí ẹni tí a lè fi ọ́ wé;+Tí mo bá ní kí n máa wí, kí n sì máa sọ nípa wọn,Wọ́n pọ̀ ju ohun tí mo lè ròyìn!+ Sáàmù 139:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Irú ìmọ̀ bẹ́ẹ̀ kọjá òye mi.* Ó kọjá ohun tí ọwọ́ mi lè tẹ̀.*+
5 Wo bí àwọn ohun tí o ṣe ti pọ̀ tó,Jèhófà Ọlọ́run mi,Àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ àti èrò rẹ sí wa.+ Kò sí ẹni tí a lè fi ọ́ wé;+Tí mo bá ní kí n máa wí, kí n sì máa sọ nípa wọn,Wọ́n pọ̀ ju ohun tí mo lè ròyìn!+