-
Jẹ́nẹ́sísì 20:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ábúráhámù bẹ̀rẹ̀ sí í rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Ọlọ́run tòótọ́, Ọlọ́run sì mú Ábímélékì àti ìyàwó rẹ̀ lára dá, pẹ̀lú àwọn ẹrúbìnrin rẹ̀, wọ́n sì wá ń bímọ;
-