Òwe 12:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ọ̀rọ̀ téèyàn sọ láìronú dà bí ìgbà tí idà gúnni,Àmọ́ ahọ́n ọlọ́gbọ́n ń woni sàn.+ Òwe 25:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Bí àwọn èso ápù oníwúrà tó wà nínú abọ́* fàdákàNi ọ̀rọ̀ tí a sọ ní àkókò tí ó tọ́.+