ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 14:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Tí a bá ti pinnu àwọn ọjọ́ rẹ̀,

      Iye oṣù rẹ̀ wà lọ́wọ́ rẹ;

      O ti pààlà fún un, kó má bàa kọjá rẹ̀.+

       6 Gbé ojú rẹ kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀ kó lè sinmi,

      Títí ó fi máa lo ọjọ́ rẹ̀ tán+ bí alágbàṣe.

  • Sáàmù 39:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 “Jèhófà, jẹ́ kí n mọ ohun tó máa gbẹ̀yìn mi

      Àti bí ọjọ́ ayé mi ṣe máa gùn tó,+

      Kí n lè mọ bí ẹ̀mí mi ṣe kúrú tó.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́