Sáàmù 6:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àárẹ̀ ti mú mi nítorí ẹ̀dùn ọkàn mi;+Láti òru mọ́jú ni omijé mi ń rin ibùsùn mi gbingbin;*Ẹkún mi ti fi omi kún àga tìmùtìmù mi.+
6 Àárẹ̀ ti mú mi nítorí ẹ̀dùn ọkàn mi;+Láti òru mọ́jú ni omijé mi ń rin ibùsùn mi gbingbin;*Ẹkún mi ti fi omi kún àga tìmùtìmù mi.+