46 Lẹ́yìn ìyẹn, Rèbékà ń tẹnu mọ́ ọn fún Ísákì pé: “Àwọn ọmọbìnrin Hétì+ ti fayé sú mi. Bí Jékọ́bù bá lọ fẹ́ ìyàwó nínú àwọn ọmọ Hétì, irú àwọn ọmọbìnrin ilẹ̀ yìí, kí làǹfààní pé mo wà láàyè?”+
4 Ó rin ìrìn ọjọ́ kan lọ sínú aginjù, ó dúró, ó jókòó sábẹ́ igi wíwẹ́, ó sì béèrè pé kí òun* kú. Ó sọ pé: “Ó tó gẹ́ẹ́! Jèhófà, gba ẹ̀mí* mi,+ nítorí mi ò sàn ju àwọn baba ńlá mi.”