Jóòbù 23:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́, ó mọ ọ̀nà tí mo gbà.+ Lẹ́yìn tó bá dán mi wò, màá wá dà bíi wúrà tí wọ́n yọ́ mọ́.+