- 
	                        
            
            Sáàmù 33:13-15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        13 Jèhófà bojú wolẹ̀ láti ọ̀run; Ó ń rí gbogbo ọmọ èèyàn.+ 14 Láti ibi tó ń gbé, Ó ń wo gbogbo àwọn tó ń gbé ayé. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 16:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        17 Nítorí ojú mi wà lára gbogbo ohun tí wọ́n ń ṣe.* Wọn ò pa mọ́ lójú mi, Bẹ́ẹ̀ ni àṣìṣe wọn kò ṣókùnkùn sí mi. 
 
-