- 
	                        
            
            1 Kíróníkà 12:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        18 Ìgbà náà ni ẹ̀mí Ọlọ́run bà lé Ámásáì,*+ olórí ọgbọ̀n ọmọ ogun, ó ní: “Tìrẹ ni wá, Dáfídì, ọ̀dọ̀ rẹ sì ni a wà, ìwọ ọmọ Jésè.+ Àlàáfíà, àlàáfíà fún ọ, àlàáfíà fún ẹni tó ń ràn ọ́ lọ́wọ́, Nítorí Ọlọ́run rẹ ń ràn ọ́ lọ́wọ́.”+ Torí náà, Dáfídì gbà wọ́n, ó sì yàn wọ́n pé kí wọ́n wà lára àwọn olórí ọmọ ogun. 
 
-