Róòmù 14:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́ kí ló dé tí o fi ń dá arákùnrin rẹ lẹ́jọ́?+ Tàbí kí ló dé tí ò ń fojú àbùkù wo arákùnrin rẹ? Nítorí gbogbo wa la máa dúró níwájú ìjókòó ìdájọ́ Ọlọ́run.+ Ìfihàn 20:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Mo rí ìtẹ́ funfun kan tó tóbi àti Ẹni tó jókòó sórí rẹ̀.+ Ayé àti ọ̀run sá kúrò níwájú rẹ̀,+ kò sì sí àyè kankan fún wọn.
10 Àmọ́ kí ló dé tí o fi ń dá arákùnrin rẹ lẹ́jọ́?+ Tàbí kí ló dé tí ò ń fojú àbùkù wo arákùnrin rẹ? Nítorí gbogbo wa la máa dúró níwájú ìjókòó ìdájọ́ Ọlọ́run.+
11 Mo rí ìtẹ́ funfun kan tó tóbi àti Ẹni tó jókòó sórí rẹ̀.+ Ayé àti ọ̀run sá kúrò níwájú rẹ̀,+ kò sì sí àyè kankan fún wọn.