Sáàmù 28:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Má ṣe fà mí lọ pẹ̀lú àwọn ẹni ibi, pẹ̀lú àwọn tó ń ṣe ohun búburú,+Àwọn tó ń bá ọmọnìkejì wọn sọ̀rọ̀ àlàáfíà, àmọ́ tó jẹ́ pé ibi ló wà lọ́kàn wọn.+ Sáàmù 62:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí wọ́n gbìmọ̀ pọ̀ láti taari rẹ̀ kúrò ní ipò gíga tó wà;*Wọ́n fẹ́ràn láti máa parọ́. Wọ́n ń fi ẹnu wọn súre, àmọ́ nínú wọn lọ́hùn-ún, wọ́n ń gégùn-ún.+ (Sélà)
3 Má ṣe fà mí lọ pẹ̀lú àwọn ẹni ibi, pẹ̀lú àwọn tó ń ṣe ohun búburú,+Àwọn tó ń bá ọmọnìkejì wọn sọ̀rọ̀ àlàáfíà, àmọ́ tó jẹ́ pé ibi ló wà lọ́kàn wọn.+
4 Nítorí wọ́n gbìmọ̀ pọ̀ láti taari rẹ̀ kúrò ní ipò gíga tó wà;*Wọ́n fẹ́ràn láti máa parọ́. Wọ́n ń fi ẹnu wọn súre, àmọ́ nínú wọn lọ́hùn-ún, wọ́n ń gégùn-ún.+ (Sélà)