Sáàmù 27:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Jèhófà ni ìmọ́lẹ̀ mi+ àti ìgbàlà mi. Ta ni èmi yóò bẹ̀rù?+ Jèhófà ni odi ààbò ayé mi.+ Ta ni èmi yóò fòyà? Sáàmù 56:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìwọ Ọlọ́run, ẹni tí mò ń yin ọ̀rọ̀ rẹ̀,Ìwọ Jèhófà, ẹni tí mò ń yin ọ̀rọ̀ rẹ̀,11 Ìwọ Ọlọ́run ni mo gbẹ́kẹ̀ lé; ẹ̀rù ò bà mí.+ Kí ni èèyàn lásánlàsàn lè fi mí ṣe?+ Róòmù 8:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Kí ni ká wá sọ sọ́rọ̀ yìí? Tí Ọlọ́run bá wà lẹ́yìn wa, ta ló lè dènà wa?+ Hébérù 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ká lè nígboyà gidigidi, ká sì sọ pé: “Jèhófà* ni olùrànlọ́wọ́ mi; mi ò ní bẹ̀rù. Kí ni èèyàn lè fi mí ṣe?”+
27 Jèhófà ni ìmọ́lẹ̀ mi+ àti ìgbàlà mi. Ta ni èmi yóò bẹ̀rù?+ Jèhófà ni odi ààbò ayé mi.+ Ta ni èmi yóò fòyà?
10 Ìwọ Ọlọ́run, ẹni tí mò ń yin ọ̀rọ̀ rẹ̀,Ìwọ Jèhófà, ẹni tí mò ń yin ọ̀rọ̀ rẹ̀,11 Ìwọ Ọlọ́run ni mo gbẹ́kẹ̀ lé; ẹ̀rù ò bà mí.+ Kí ni èèyàn lásánlàsàn lè fi mí ṣe?+
6 Ká lè nígboyà gidigidi, ká sì sọ pé: “Jèhófà* ni olùrànlọ́wọ́ mi; mi ò ní bẹ̀rù. Kí ni èèyàn lè fi mí ṣe?”+