Jóòbù 33:29, 30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Lóòótọ́, Ọlọ́run máa ń ṣe gbogbo nǹkan yìíFún èèyàn, lẹ́ẹ̀mejì, lẹ́ẹ̀mẹta,30 Láti mú un* pa dà kúrò nínú kòtò,*Kí ìmọ́lẹ̀ ìyè+ lè là á lóye.
29 Lóòótọ́, Ọlọ́run máa ń ṣe gbogbo nǹkan yìíFún èèyàn, lẹ́ẹ̀mejì, lẹ́ẹ̀mẹta,30 Láti mú un* pa dà kúrò nínú kòtò,*Kí ìmọ́lẹ̀ ìyè+ lè là á lóye.