Sáàmù 46:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Ọlọ́run ni ibi ààbò wa àti okun wa,+Ìrànlọ́wọ́ tó wà lárọ̀ọ́wọ́tó ní àkókò wàhálà.+ Sáàmù 54:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí o gbà mí nínú gbogbo wàhálà,+Màá sì máa wo ìṣubú àwọn ọ̀tá mi.+