- 
	                        
            
            1 Sámúẹ́lì 19:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        12 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Míkálì sọ Dáfídì kalẹ̀ gba ojú fèrèsé,* kí ó lè sá àsálà. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 18:48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        48 Ó ń gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi tí inú ń bí; Ìwọ gbé mi lékè àwọn tó ń gbéjà kò mí;+ O gbà mí lọ́wọ́ oníwà ipá. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 71:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        4 Ọlọ́run mi, gbà mí lọ́wọ́ ẹni burúkú,+ Gbà mí lọ́wọ́ àwọn tó ń ni èèyàn lára láìtọ́. 
 
-