- 
	                        
            
            Sáàmù 109:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        2 Nítorí àwọn ẹni burúkú àti àwọn ẹlẹ́tàn ń la ẹnu wọn sí mi. Wọ́n ń fi ahọ́n èké sọ̀rọ̀ nípa mi;+ - 
	                        
            
            Sáàmù 109:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        10 Kí àwọn ọmọ* rẹ̀ máa tọrọ nǹkan kiri, Kí wọ́n sì máa jáde látinú ilé wọn tó ti di ahoro lọ wá oúnjẹ. 
 
- 
                                        
 
- 
	                        
            
            
 
-