Sáàmù 18:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ọlọ́run tòótọ́ ni ẹni tó ń gbé agbára wọ̀ mí,+Yóò sì mú kí ọ̀nà mi jẹ́ pípé.+