Jónà 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 ó sì sọ pé: “Mo ké pe Jèhófà nígbà tí mo wà nínú ìṣòro, ó sì dá mi lóhùn.+ Láti inú* Isà Òkú* ni mo ti kígbe pé kí o ràn mí lọ́wọ́.+ O sì gbọ́ ohùn mi.
2 ó sì sọ pé: “Mo ké pe Jèhófà nígbà tí mo wà nínú ìṣòro, ó sì dá mi lóhùn.+ Láti inú* Isà Òkú* ni mo ti kígbe pé kí o ràn mí lọ́wọ́.+ O sì gbọ́ ohùn mi.