Sáàmù 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní tèmi, ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé;+Àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ yóò máa mú ọkàn mi yọ̀.+ Sáàmù 20:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 A ó kígbe ayọ̀ nítorí àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ;+A ó gbé àwọn ọ̀págun wa sókè ní orúkọ Ọlọ́run wa.+ Kí Jèhófà dáhùn gbogbo ohun tí o béèrè.
5 A ó kígbe ayọ̀ nítorí àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ;+A ó gbé àwọn ọ̀págun wa sókè ní orúkọ Ọlọ́run wa.+ Kí Jèhófà dáhùn gbogbo ohun tí o béèrè.