Sáàmù 62:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 62 Ní tòótọ́, mo* dúró jẹ́ẹ́ de Ọlọ́run. Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni ìgbàlà mi ti wá.+ 2 Ní tòótọ́, òun ni àpáta mi àti ìgbàlà mi, ibi ààbò mi;*+Mìmì kan ò ní mì mí débi tí màá ṣubú.+ Sáàmù 71:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí ìwọ ni ìrètí mi, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ;Ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé* láti ìgbà èwe mi wá.+
62 Ní tòótọ́, mo* dúró jẹ́ẹ́ de Ọlọ́run. Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni ìgbàlà mi ti wá.+ 2 Ní tòótọ́, òun ni àpáta mi àti ìgbàlà mi, ibi ààbò mi;*+Mìmì kan ò ní mì mí débi tí màá ṣubú.+