Àìsáyà 40:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Wò ó! Àwọn orílẹ̀-èdè dà bí ẹ̀kán omi kan látinú korobá,A sì kà wọ́n sí eruku fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ lórí òṣùwọ̀n.+ Wò ó! Ó ń gbé àwọn erékùṣù sókè bí eruku lẹ́búlẹ́bú.
15 Wò ó! Àwọn orílẹ̀-èdè dà bí ẹ̀kán omi kan látinú korobá,A sì kà wọ́n sí eruku fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ lórí òṣùwọ̀n.+ Wò ó! Ó ń gbé àwọn erékùṣù sókè bí eruku lẹ́búlẹ́bú.