Òwe 12:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀rọ̀ burúkú tó ń jáde lẹ́nu ẹni ibi ló ń dẹkùn mú un,+Àmọ́ olódodo ń bọ́ lọ́wọ́ wàhálà. Òwe 18:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹnu òmùgọ̀ ni ìparun rẹ̀,+Ètè rẹ̀ sì jẹ́ ìdẹkùn fún ẹ̀mí* rẹ̀.