- 
	                        
            
            Sáàmù 21:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        9 Wàá ṣe wọ́n bí ohun tí a jù sínú iná ìléru ní àkókò tí o yàn láti fiyè sí wọn. Jèhófà máa gbé wọn mì nínú ìbínú rẹ̀, iná á sì jó wọn run.+ 
 
-