-
Àìsáyà 30:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ẹ̀ṣẹ̀ yìí máa dà bí ògiri tó ti sán fún yín,
Bí ògiri gíga tó wú, tó máa tó wó,
Ó máa wó lójijì, ká tó ṣẹ́jú pẹ́.
-
13 Ẹ̀ṣẹ̀ yìí máa dà bí ògiri tó ti sán fún yín,
Bí ògiri gíga tó wú, tó máa tó wó,
Ó máa wó lójijì, ká tó ṣẹ́jú pẹ́.