Jóṣúà 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 gbàrà tí àtẹ́lẹsẹ̀ àwọn àlùfáà tó gbé Àpótí Jèhófà, Olúwa gbogbo ayé bá kan* omi Jọ́dánì, omi Jọ́dánì tó ń ṣàn wá látòkè máa dáwọ́ dúró, ó sì máa dúró bí ìsédò.”*+
13 gbàrà tí àtẹ́lẹsẹ̀ àwọn àlùfáà tó gbé Àpótí Jèhófà, Olúwa gbogbo ayé bá kan* omi Jọ́dánì, omi Jọ́dánì tó ń ṣàn wá látòkè máa dáwọ́ dúró, ó sì máa dúró bí ìsédò.”*+