7 Àwọn èèyàn náà wá bá Mósè, wọ́n sì sọ pé: “A ti ṣẹ̀, torí a ti sọ̀rọ̀ sí Jèhófà àti ìwọ.+ Bá wa bẹ Jèhófà pé kó mú àwọn ejò náà kúrò lọ́dọ̀ wa.” Mósè sì bá àwọn èèyàn+ náà bẹ̀bẹ̀.
3 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ké pe Jèhófà,+ torí pé Jábínì* ní ọgọ́rùn-ún mẹ́sàn-án (900) kẹ̀kẹ́ ogun tó ní dòjé irin,*+ ogún (20) ọdún ló sì fi fìyà jẹ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gidigidi.+