- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 9:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        25 Yìnyín náà bọ́ lu gbogbo ohun tó wà nínú oko ní gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì, látorí èèyàn dórí ẹranko, ó run gbogbo ewéko, ó sì run gbogbo igi oko.+ 
 
-