-
1 Sámúẹ́lì 4:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Àwọn Filísínì tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti bá Ísírẹ́lì jà, àmọ́ ìjà náà yíwọ́, àwọn Filísínì ṣẹ́gun Ísírẹ́lì, wọ́n pa nǹkan bí ẹgbẹ̀rún mẹ́rin (4,000) ọkùnrin lójú ogun ní pápá.
-
-
1 Sámúẹ́lì 4:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Torí náà, àwọn Filísínì jà, wọ́n ṣẹ́gun Ísírẹ́lì,+ kálukú wọn sì sá lọ sí ilé rẹ̀. Ìpakúpa náà pọ̀; ọ̀kẹ́ kan ààbọ̀ (30,000) àwọn ọmọ ogun tó ń fẹsẹ̀ rìn ló kú lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.
-