- 
	                        
            
            2 Sámúẹ́lì 6:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        21 Ni Dáfídì bá sọ fún Míkálì pé: “Iwájú Jèhófà ni mo ti ń ṣe àjọyọ̀, òun ni ó yàn mí dípò bàbá rẹ àti gbogbo agbo ilé rẹ̀ láti fi mí ṣe aṣáájú Ísírẹ́lì+ tó jẹ́ àwọn èèyàn Jèhófà. Torí náà, màá ṣe àjọyọ̀ níwájú Jèhófà, 
 
-