-
Sáàmù 44:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 O sọ wá di ẹni ẹ̀gàn lójú àwọn aládùúgbò wa,
Ẹni ẹ̀sín àti ẹni yẹ̀yẹ́ lójú àwọn tó yí wa ká.
-
-
Sáàmù 79:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 A ti di ẹni ẹ̀gàn lójú àwọn aládùúgbò wa;+
Àwọn tó yí wa ká ń fi wá ṣẹ̀sín, wọ́n sì ń fi wá ṣe yẹ̀yẹ́.
-