- 
	                        
            
            Náhúmù 2:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        2 Nítorí Jèhófà yóò dá ògo Jékọ́bù pa dà, Yóò dá a pa dà sí ògo Ísírẹ́lì, Nítorí àwọn apanirun ti pa wọ́n run;+ Wọ́n sì ti pa àwọn ọ̀mùnú wọn run. 
 
-