Léfítíkù 26:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Màá sì rántí májẹ̀mú tí mo bá Jékọ́bù dá+ àti májẹ̀mú tí mo bá Ísákì dá,+ màá rántí májẹ̀mú tí mo bá Ábúráhámù dá,+ màá sì rántí ilẹ̀ náà. Jóẹ́lì 2:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Jèhófà yóò ní ìtara nítorí ilẹ̀ rẹ̀,Yóò sì ṣàánú àwọn èèyàn rẹ̀.+
42 Màá sì rántí májẹ̀mú tí mo bá Jékọ́bù dá+ àti májẹ̀mú tí mo bá Ísákì dá,+ màá rántí májẹ̀mú tí mo bá Ábúráhámù dá,+ màá sì rántí ilẹ̀ náà.