- 
	                        
            
            Jeremáyà 50:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        20 “Ní ọjọ́ yẹn àti ní àkókò yẹn,” ni Jèhófà wí, “A ó wá ẹ̀bi Ísírẹ́lì kiri, Ṣùgbọ́n a kò ní rí ìkankan, A kò sì ní rí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ Júdà, Nítorí màá dárí ji àwọn tí mo jẹ́ kí ó ṣẹ́ kù.”+ 
 
-