Diutarónómì 8:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Tí o bá sọ lọ́kàn rẹ pé, ‘Agbára mi àti iṣẹ́ ọwọ́ mi ló sọ mí di ọlọ́rọ̀,’+ 18 rántí pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ ló fún ọ lágbára láti di ọlọ́rọ̀,+ kó lè mú májẹ̀mú rẹ̀ tó bá àwọn baba ńlá rẹ dá ṣẹ, bó ṣe rí lónìí.+ Sáàmù 78:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn yìí á wá gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run. Wọn ò ní gbàgbé àwọn iṣẹ́ Ọlọ́run+Kàkà bẹ́ẹ̀, wọ́n á máa pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́.+
17 Tí o bá sọ lọ́kàn rẹ pé, ‘Agbára mi àti iṣẹ́ ọwọ́ mi ló sọ mí di ọlọ́rọ̀,’+ 18 rántí pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ ló fún ọ lágbára láti di ọlọ́rọ̀,+ kó lè mú májẹ̀mú rẹ̀ tó bá àwọn baba ńlá rẹ dá ṣẹ, bó ṣe rí lónìí.+
7 Àwọn yìí á wá gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run. Wọn ò ní gbàgbé àwọn iṣẹ́ Ọlọ́run+Kàkà bẹ́ẹ̀, wọ́n á máa pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́.+