- 
	                        
            
            Sáàmù 116:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        7 Kí ọkàn* mi rí ìsinmi lẹ́ẹ̀kan sí i, Nítorí Jèhófà ti fi inú rere hàn sí mi. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 119:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        17 Ṣe dáadáa sí èmi ìránṣẹ́ rẹ, Kí n lè wà láàyè, kí n sì máa pa ọ̀rọ̀ rẹ mọ́.+ 
 
-