1 Kọ́ríńtì 10:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 nítorí pé “Jèhófà* ló ni ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀.”+