Jóṣúà 19:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ààlà náà sì dé Tábórì,+ Ṣáhásúmà àti Bẹti-ṣémẹ́ṣì, ààlà wọn wá parí sí Jọ́dánì, gbogbo rẹ̀ jẹ́ ìlú mẹ́rìndínlógún (16) pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn. 23 Èyí ni ogún ẹ̀yà Ísákà ní ìdílé-ìdílé,+ àwọn ìlú náà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
22 Ààlà náà sì dé Tábórì,+ Ṣáhásúmà àti Bẹti-ṣémẹ́ṣì, ààlà wọn wá parí sí Jọ́dánì, gbogbo rẹ̀ jẹ́ ìlú mẹ́rìndínlógún (16) pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn. 23 Èyí ni ogún ẹ̀yà Ísákà ní ìdílé-ìdílé,+ àwọn ìlú náà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.