ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 7:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ kò ní kúrò lára rẹ̀ bí mo ṣe mú un kúrò lára Sọ́ọ̀lù,+ ẹni tí mo mú kúrò níwájú rẹ.

  • 1 Kíróníkà 17:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Màá di bàbá rẹ̀, á sì di ọmọ mi.+ Mi ò ní mú ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ kúrò lára rẹ̀+ bí mo ṣe mú un kúrò lára ẹni tó ṣáájú rẹ.+

  • Ìṣe 13:34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Bí Ó ṣe jí i dìde nínú ikú, tí kò sì jẹ́ kó pa dà sí ara tó lè díbàjẹ́ mọ́, ó sọ ọ́ lọ́nà yìí pé: ‘Màá fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tí mo ṣèlérí fún Dáfídì hàn sí ọ, èyí tó jẹ́ òtítọ́.’*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́