Sáàmù 14:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Òmùgọ̀* sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: “Kò sí Jèhófà.”+ Ìwà ìbàjẹ́ ni wọ́n ń hù, ìṣesí wọn sì jẹ́ ohun ìríra;Kò sí ẹni tó ń ṣe rere.+ 1 Kọ́ríńtì 2:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ẹni ti ara kì í tẹ́wọ́ gba* àwọn nǹkan ti ẹ̀mí Ọlọ́run, torí wọ́n jẹ́ nǹkan òmùgọ̀ lójú rẹ̀; kò sì lè mọ̀ wọ́n, nítorí ẹ̀mí la fi ń wádìí wọn.
14 Òmùgọ̀* sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: “Kò sí Jèhófà.”+ Ìwà ìbàjẹ́ ni wọ́n ń hù, ìṣesí wọn sì jẹ́ ohun ìríra;Kò sí ẹni tó ń ṣe rere.+
14 Ẹni ti ara kì í tẹ́wọ́ gba* àwọn nǹkan ti ẹ̀mí Ọlọ́run, torí wọ́n jẹ́ nǹkan òmùgọ̀ lójú rẹ̀; kò sì lè mọ̀ wọ́n, nítorí ẹ̀mí la fi ń wádìí wọn.