1 Kọ́ríńtì 3:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àti pé: “Jèhófà* mọ̀ pé èrò àwọn ọlọ́gbọ́n jẹ́ ìmúlẹ̀mófo.”+