Jẹ́nẹ́sísì 1:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Kí àwọn omi tó wà lábẹ́ ọ̀run wọ́ jọ síbì kan, kí ilẹ̀ sì fara hàn.”+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀. 10 Ọlọ́run pe ilẹ̀ náà ní Ayé,+ àmọ́ ó pe omi tó wọ́ jọ ní Òkun.+ Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.+
9 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Kí àwọn omi tó wà lábẹ́ ọ̀run wọ́ jọ síbì kan, kí ilẹ̀ sì fara hàn.”+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀. 10 Ọlọ́run pe ilẹ̀ náà ní Ayé,+ àmọ́ ó pe omi tó wọ́ jọ ní Òkun.+ Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.+